"Ko fi ọrọ kankan siłę. O ti ku nigba ti wọn gbe lọ," Hafiza sọrọ jẹjẹ bi o ṣe n ṣalaye bi won ṣe ṣekupa iya rẹ ni ilu kan ni Darfue lasiko ogun abẹle ni Sudan to bẹrẹ ni odun meji sẹyin. ẹni ọdun ...
Eemọ ati kayefi parapọ̀, wọn bẹ silẹ ni ilu Kaiama ni ipinlẹ Kwara nibi ti iroyin ti jade pe arakunrin kan n ba iya rẹ lajọsepọ ti ọmọ mẹta si ti tara Ibalopọ wọn jade. BBC Yoruba gbọ pé àwọn to n se ...
Tiago Gomes, ti o n pe ara re ni Oyinbo Ibile bawa soro lori ife re fun èdè Yorùbá. Iya re na, Dr Paula Gomes bawa soro. Won si pe akiyesi awon omo Yoruba si iwolu ati ki karamasiki iwa and àṣà èdè ...